Journalism
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Iṣẹ́ ìròyìn jẹ́ kíkọ àti pínpínká àwọn àpilẹ̀kọ bíi : ìtàkurọ̀sọ, ìṣẹ̀lẹ̀, òkodoro-ọ̀rọ̀, ìròrí àti àpilẹ̀kọ nípa àwọn ènìyàn tí wọ́n jẹyọ nínú ìròyìn ojoojúmọ́ láti fi ṣe ìfitónilétí fún àwọn ènìyàn àwùjlóòrèkóòrè. Gbólóhùn ìròyìn jẹ́ ohun tí a lè fi sọrí àwọn tí wọ́n ń kó ohun tí a mọ̀ sí ojúlówó ìròyìn jọ kí etí àwọn ènìyàn àwùjọ ó má ba gbófo, òníọ̀hún jẹ́ akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ ni tàbí bẹ́ẹ̀ kọ́. Iṣẹ́ oníròyìn yàtọ síra wọn ní ìlú ati orílẹ̀-èdè sí orílẹ̀-èdè. Ní àwọn orílẹ̀-èdè kan, iṣẹ́ ìròyìn àti àwọn oníròyìn kò dá dúró nítorí wípé ìjọba ni ó ń ṣakóso rẹ̀. [1] l. Bá kan náà ni iṣẹ́ ìròyìn ati àwọn oníròyìn náà ń da ṣíṣẹ́ tí wọn kò sì sí lábẹ́ àkóso ìjọba ní orílẹ̀-èdè míràn. Bẹ́ẹ̀ sì ni orísiríṣi òfin tí ó ń de iṣẹ́ ìròyìn yàtọ̀ síra wọn ní orílẹ̀-èdè sí orílẹ̀-èdè èyí ti ó nííṣe pẹ̀lú ànfaní ẹ̀tọ́ ìsọ̀rọ̀ láìsí ìfòyà, ẹ̀tọ́ ìkóròyìn jọ tàbí fífi ìròyìn lède, tí ó fi mọ́ ìbanilórúkọ jẹ́ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Dídé internet ati awọn fóònù ti mú ìyàtọ̀ tó pinminrin bá iṣẹ́ ìkóròyìn jọ láti ibẹ̀rẹ̀ ẹgbàá ọdún tí a wà yí (2000). Púpọ̀ àwọn ònkàròyìn ni wọ́n yí padà kúrò níbi kí wọ́ ma ka ìròyìn láti oríÌwé-ìròyìn olójoojúmọ́, Ìwé-ìròyìn àtìgbà-dégbà, tàbí kí wọ́n jókòó sídí ẹ̀rọ rédíò láti gbọ́ ìròyìn tí wọ́n sì ti ń ka àwọn ìròyìn ọlọ́kan-ò-jọkan lórí fóònù wọn. Gbogbo ilé-iṣẹ́ ìròyìn pátá náà ni eọ́ ti gbọ́n já ìlànà ọ̀tun tí internet mú wọ inú iṣẹ́ wọn tí àwọn náà sì tj sọ gbogbo ojú òpó ìròyìn wọn dowó, nítorí wípé tìrẹ Ìwé-ìròyìn jáde kò fi bẹ́ẹ̀ gbajúmọ̀ mọ́ tí owó tí wọ́n ń pa níbẹ̀ náà ti dínkù jọjọ.[2]
Remove ads
Ìgbéjade ìròyìn
Ìpinu nípa gbígbé ìròyìn jáde yàtọ̀ síra w9n ní orílẹ̀-èdè sí orílẹ̀-èdè, ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà, àwọn ilé-iṣẹ́ ńlá ńlá ni wọ́n ń gbé ìròyìn jáde, bákan náà ni àwọn èyàn kan tí Won ń pe ní búlọ́gà náà ma ń gbé ìròyìn jáde bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé ó wà lábẹ́ ofin Federal Trade Commission ti Amẹ́ríka kí àwọn búlọ́gà ó gba ẹ̀bùn bí owó tabi nkan miran fún ìròyìn tàbí ìpolówó tí wọ́n bá ṣe fún àjọ tàbí ènìyàn kan, wọ́n sì gbọdọ̀ sọ ohun tí wọ́n bá gbà náà gẹ́gẹ́ bí ẹ̀bùn ọ̀fẹ́. Ìjọba Amẹ́ríkà gbé òfin yí kalẹ̀ láti lè dáàbò bo irúfẹ́ ìròyìn tí àwọn ènìyàn ń kà lórí ẹ̀rọ ayélujára.[3] Àwọn ìròyin tó fẹsẹ̀ múlẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà ni wọ́n ma ń ti ilé-iṣẹ́ ìròyìn gidi jáde tí wọ́n sì ní awọn olóòtú ìròyìn lóríṣirí, tí wọ́n sì tún ní ẹ̀ka ìpolówó ọ̀jà tí ìṣeẹ́ wọn kò sì papọ̀ tàbí tako ara wọn. Púpọ̀ ní irúfẹ́ àwọn ilé-iṣẹ́ ìròyìn ńlá ńlá wọ̀nyí ni wọ́n ma ń gba àwọn akọ́ṣẹ́-mọṣẹ́ nípa iṣẹ́ ìròyìn síṣẹ́ nílé iṣẹ́ wọn, tí àwọn náà sì wà lábẹ́ àkóso American Society of News Editors, Society of Professional Journalist, Investigative Reporters & Èsì tó rà, Inú tàbí Oline News Association. Bákan náà ni àwọn ilé-iṣẹ́ Ìwé-ìròyìn kọ̀ọ̀kan ni wọ́n ní òfin àti àlàkalẹ̀ tí yóò ma jẹ́ ìlànà fún gbogbo òṣìṣẹ̀ wọn. Àpẹẹrẹ irúfẹ́ ilé-iṣẹ́ Ìwé-ìròyìn bẹ́ẹ̀ ni The New York Times .[4] Nígbà tí wọ́n bá ń ṣàpilẹ̀kọ ìròyìn, ìkọ̀ròyìn òtítọ́ kí ó sì má fi ìròyìn ṣ'ègbè ni ó jẹ ònkàọ̀ròyìn lógún. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé àwọn ìròyìn kan ma ń ṣàfihàn èrò ònkọ̀ròyìn, àmọ́ èyí tí ó jẹ́ ojúlówó ni kí wọ́n gbé ìròyìn kalẹ̀ láì fi síbì kan. Ìròyìn ma ń wà ní ìsọ̀rí ìsọ̀rí yálà nínú Ìwé-ìròyìn ni tabi torí ẹ̀rọ ayélujára, èyí ma ń jẹ́ kí ìròyìn ó fẹsẹ̀ múlẹ̀ kí ó sì yàtọ̀ sí èrò ònkọ̀ròyìn lásán. Àwọn ònkaròyìn gbọ́dọ̀ ní àkíyèsí sí àwọn àkòrí ìròyìn kí wọ́n lè mọ ìyàtọ̀ sí èrò lásán ati òkodoro ọ̀rọ̀. Àwọn àròkọ tí wọ́n jẹ́ èrò ònkọ̀ròyìn tàbí ti olóòtú ni wọ́n sábà ma ń wà ní abẹ́ Èrò tàbí Èrò tiwa.[5] Àwọn ìròyìn tó jẹyọ, ìròyìn yàjó-yajó àti ìròyìn tó le koko ni wọ́n ma ń wà ní inú Ìwé-ìròyìn. Gẹ́gẹ́ bí Robert McChesney, sọ wípé iṣẹ́ ìròyìn tó lálàáfíà tó ń fi ìjọba awa ara wa hàn gbọ́dọ̀ lè yànàná èrò àwọn tó dipò ìjọba mú ati àwọn tí wọ́n fẹ́ dipò ìṣèjọba mú. Ó gbọ́dọ̀ ṣafihan èrò orísirísi kí ó sì kọ nípa àwọn ohun tí ó ṣe pàtàkì fún aráàlú láti gbọ́.[6]
Orísiríṣi aríyànjiyan ni ó ti wáyé lórí Ṣé ó yẹ kí oníròyìn fi èròngbà rẹ̀ hàn tàbí kí ó yẹra fún ìṣàfikún èrò sínú ìròyìn. Aríyànjiyan yí tún fi múlẹ̀ wípé ònkọ̀ròyìn ma ń kọ ìròyìn lórí kókó kan tí ó jẹyọ nínú awùjọ tí òfin ati ìlànà ìṣeẹ́ ìròyìn sì ma ń jẹ́ atọ́nà wọn láti kọ ohun tí ó jẹ́ ojúlówó ìròyìn látara kókó ọ̀rọ̀ náà fún àwùjọ náà. Láfikún, aríyànjiyan yí tún fi múlẹ̀ wípé iṣẹ́ ònkọ̀ròyìn ni láti kọ ìròyìn pẹ̀lú àwọn ọnà-èdè tó peregedé láti inú àgbàọ́nọ̀gbẹ ìmọ̀ èdè rẹ̀ láti fi yànàná kókó-ọ̀rọ̀ náà fáyégbọ́.[7]
Remove ads
Ìsọ̀rí iṣẹ́ ìròyìn
Orísiríṣi ìsọ̀rí ni iṣẹ́ ìròyìn pín sí. Ojúṣe iṣẹ́ ìròyìn ni láti ma ṣọ́ ìṣesí ìjọba àti àwùjọ lowọ́-lẹ́sẹ̀. Agbékalẹ̀ ìsọ̀rí ìròyìn kan ni ó sábà ma ń kò àwọn orísiríṣi ìsọ̀rí ìròyìn sínú, èyí tí ó yàtọ̀ síra wọn. Ìpínsísọ̀rí ìwé ìròyìn tabi ará website wọn ni ó ma ń pèsè ìròyìn fún àwọn ònkaròyìn.[8][9]


Lára àwọn ìsọ̀rí náà ni:
- Access journalism – jẹ́ Oníròyìn tó kóra rẹ̀ níjánu láti má sọ ohun tí ó lè tàbùkù ẹni tí wọ́n ń fọ̀rọ̀ wá lẹ́nu wò.
- Advocacy journalism – Oníròyìn tí ó gbé ìròyìn ìlanilọ́yẹ̀ jáde fún ará ìlú.
- Broadcast journalism – Ìròyìn tí a kọ tàbí kà lórí rédíò tàbí tẹlifíṣàn.
Journalists in the Radio-Canada/CBC newsroom in Montreal, Canada

- Business journalism - Ìròyìn tí ó ń ṣàlayé., yànàná okòwò, ìṣúná, ìṣesí àti ìhùmàsí tí ó rọ̀ mọ́ àwùjọ.
- Citizen journalism – participatory journalism.
- Data journalism – Ìròyìn bí wọ́n ṣe ń sọ ìtàn nípa lílo numbà. Oníròyìn yí lè lo data láti fi kín apilẹ̀kọ rẹ̀ lẹ́yìn. Bákan náà ni wọ́n tún lè ṣe àtúntò sí numba ati data tí ó ti wà nílẹ̀.
- Drone journalism – Lílo drones láti fi ká ìṣẹ̀lẹ̀.[10]
- Gonzo journalism – ni ọ̀gbẹ́ni Hunter S. Thompson, kọ́kọ́ gbé kalẹ̀ tí ó ni Ṣé pẹ̀lú ọgbọ́n àtinúdá láti fi ṣèròyìn.[11]
- Interactive journalism – orísi ìròyìn tí eọ́n ń gbé kalẹ̀ lórí ará website.
- Investigative journalism – ni iṣẹ́ ìròyìn tí ó ṣèwádí ìwà ìbàjẹ́ àwùjọ.
- Photojournalism –ni iṣẹ́ ìròyìn tí wọ́n fi ma ń fi àwòrán ṣèròyìn.
- Political journalism - ni iṣẹ́ ìròyìn tí wọ́n fi ń wòye ipa ìṣèlú láàrín àwùjọ.
- Sensor journalism – the use of sensors to support journalistic inquiry
- Sports journalism - writing ni wọ́n fi ń ṣèròyìn nípa eré ìdárayá.compet
- Tabloid journalism – writing that is light-hearted and entertaining. Considered less legitimate than mainstream journalism.
- Yellow journalism (or sensationalism) – writing which emphasizes exaggerated claims or rumors.
- Global journalism - journalism that encompasses a global outlook focusing on intercontinental issues.
- War journalism - the covering of wars and armed conflicts
Ojú òpó ìkànsíraẹni
Dídé tí ojú òpó ìkànsíraẹni tí wọ́n ń pe ní social media ti mú ìyípadà tó ṣàra-ọ̀tọ̀ bá ìjábọ̀ ìròyìn tí ó sì mú itẹ̀síwájú bá ìṣeẹ́ ìròyìn lórí ẹ̀rọ ayélujára. Nínú ìwáfí tí àwọn kan ṣe ní ọdún 2014, púpọ̀ nínú àwọn ènìyàn ilẹ̀ Amẹ́ríkà ni wọ́n sọ wípé àwọn ma ń sábà gbáralé ìròyìn orí ẹ̀rọ ayélujára ju kí àwọn ó ra Ìwé-ìròyìn tí wọ́n ń tẹ̀ jáde ní ojoojúmọ́. [12] From this, the conclusion can be drawn that breaking news nowadays often stems from user-generated content, including videos and pictures posted online in social media.[12] Ìdá ọgọ́ta nínú àwọn oníṣẹ́ ìròyìn tí wọ́n ń lo ojú òpó ayélujára ni wọ́n sọ wípé àwọn ma ń yára kàn sí àwọn olólùfẹ́ tí wọ́n sì ń tẹ̀lé ojú òpó wọn ní wàrànṣeṣà. Nígbà tí ìdá ọgbọ̀n gbà wípé ojú òpó ìkànsíraẹni ti mú ìyípadà tó gbópọn bá iṣẹ́ ìròyìn.[12] Láfikún, ìwádí tí Pew Research Center ṣe fi múlẹ̀ wípé ìdá mẹ́jọ nínú mẹ́wá àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́rika ni wọ́n ń ṣamúlò ìròyìn lórí érọ ayélujára ju ìwé ìròyìn lọ. [13].
Ìròyìn ẹlẹ́jẹ̀
Ìròyìn ẹlẹ́jẹ̀ ni a lè pè ní ìró tàbí ìròyìn òfegè tí kìí ṣe òótọ́ tí àwọn ènìyàn kan tàbí àwọn ẹgbẹ́ kan tí wọ́n fẹ́ fi ìròyìn ọ̀hún da rúgúdù sílẹ̀ láàrín ìlú tàbí agbègbè kan, tí ìròyìn náà sì ma ń ràn mọ̀ọ̀ bí iná inú pápá. Wọ́n ma ń gbé ìròyìn ẹlẹ́jẹ̀ kalẹ̀ pẹ̀lú èrò láti fi ṣi àwọn ènìyàn lọ́nà nípa nkan tàbí ènìyàn. Àpẹẹrẹ ni bí wọ́n ṣe gbé ìròyìn kan tí kìí ṣe òótọ́ jáde ní arabìnrin Hillary Clinton tí ó tún jẹ́ adíje dupò nínú ìdìbò sípò ààrẹ ní ọdún 2015 ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà léte ati fi ba obìnrin náà lórúkọ jẹ́.[14] Púpò nínú àwọn ìròyìn wọ̀nyí ni wón ma ń lo ojú òpó ìbánidọ́rẹ́ Facebook, Twitter ati TikTok láti fi pín irúfẹ́ ìròyìn náà ká láti fi bani lórúkọ jẹ́.[15] Àwọn alámùúlò àwọn ojú-òpó ìbánisọ̀rọ̀ tí a ti mẹ́nu bá wọ̀nyí lánfàní láti ṣe àgbéyẹwò irúfẹ́ ìròyìn tí wọ́n bá bá pàdé lórí àwọn ìkanì náà.
The phrase was popularized and used by Donald Trump during his presidential campaign to discredit what he perceived as negative news coverage of his candidacy and then the presidency.[16]
In some countries, including Turkey,[17] Egypt,[18] India,[19] Bangladesh,[20] Iran,[21] Nigeria,[22] Ethiopia,[23] Kenya,[24] Cote d’Ivoire,[25] Montenegro,[26] Kazakhstan,[27] Azerbaijan,[28] Malaysia,[29] Singapore,[30] Philippines,[31] and Somalia[32] journalists have been threatened or arrested for allegedly spreading fake news about the COVID-19 pandemic.
Radio
Radio broadcasting increased in popularity starting in the 1920s, becoming widespread in the 1930s. While most radio programming was oriented toward music, sports, and entertainment, radio also broadcast speeches and occasional news programming. Radio reached the peak of its importance during World War II, as radio and newsreels were major sources of up-to-date information on the ongoing war. In the Soviet Union, radio would be heavily utilized by the state to broadcast political speeches by leadership. These broadcasts would very rarely have any additional editorial content or analysis, setting them apart from modern news reporting.[33] The radio would however soon be eclipsed by broadcast television starting in the 1950s.
Television
Starting in the 1940s, United States broadcast television channels would air 10-to-15-minute segments of news programming one or two times per evening. The era of live-TV news coverage would begin in the 1960s with the assassination of John F. Kennedy, broadcast and reported to live on a variety of nationally syndicated television channels. During the 60s and 70s, television channels would begin adding regular morning or midday news shows. Starting in 1980 with the establishment of CNN, news channels began providing 24-hour news coverage, a format which persists through today.
Remove ads
Ethics and standards

While various existing codes have some differences, most share common elements including the principles of – truthfulness, accuracy, objectivity, impartiality, fairness and public accountability – as these apply to the acquisition of newsworthy information and its subsequent dissemination to the public.[34][35][36][37][38]
Bill Kovach and Tom Rosenstiel propose several guidelines for journalists in their book The Elements of Journalism.[39] Their view is that journalism's first loyalty is to the citizenry and that journalists are thus obliged to tell the truth and must serve as an independent monitor of powerful individuals and institutions within society. In this view, the essence of journalism is to provide citizens with reliable information through the discipline of verification.
Some journalistic Codes of Ethics, notably the European ones,[40] also include a concern with discriminatory references in news based on race, religion, sexual orientation, and physical or mental disabilities.[41][42][43][44] The Parliamentary Assembly of the Council of Europe approved in 1993 Resolution 1003 on the Ethics of Journalism which recommends journalists to respect the presumption of innocence, in particular in cases that are still sub judice.[45]
In the UK, all newspapers are bound by the Code of Practice of the Independent Press Standards Organisation. This includes points like respecting people's privacy and ensuring accuracy. However, the Media Standards Trust has criticized the PCC, claiming it needs to be radically changed to secure the public trust of newspapers.
This is in stark contrast to the media climate prior to the 20th century, where the media market was dominated by smaller newspapers and pamphleteers who usually had an overt and often radical agenda, with no presumption of balance or objectivity.
Because of the pressure on journalists to report news promptly and before their competitors, factual errors occur more frequently than in writing produced and edited under less time pressure. Thus a typical issue of a major daily newspaper may contain several corrections of articles published the previous day. Perhaps the most famous journalistic mistake caused by time pressure was the Dewey Defeats Truman edition of the Chicago Daily Tribune, based on early election returns that failed to anticipate the actual result of the 1948 US presidential election.
Codes of ethics
There are over 242 codes of ethics in journalism that vary across various regions of the world.[46] The codes of ethics are created through an interaction of different groups of people such as the public and journalists themselves. Most of the codes of ethics serve as a representation of the economic and political beliefs of the society where the code was written.[46] Despite the fact that there are a variety of codes of ethics, some of the core elements present in all codes are: remaining objective, providing the truth, and being honest.[46]
Journalism does not have a universal code of conduct; individuals are not legally obliged to follow a certain set of rules like a doctor or a lawyer does.[47] There have been discussions for creating a universal code of conduct in journalism. One suggestion centers on having three claims for credibility, justifiable consequence, and the claim of humanity.[48] Within the claim of credibility, journalists are expected to provide the public with reliable and trustworthy information, and allowing the public to question the nature of the information and its acquisition. The second claim of justifiable consequences centers on weighing the benefits and detriments of a potentially harmful story and acting accordingly. An example of justifiable consequence is exposing a professional with dubious practices; on the other hand, acting within justifiable consequence means writing compassionately about a family in mourning. The third claim is the claim of humanity which states that journalists are writing for a global population and therefore must serve everyone globally in their work, avoiding smaller loyalties to country, city, etc.[48]
Remove ads
See also
- Citizen journalism
- Fourth Estate
- Glossary of journalism
- Investigative journalism
- Hallin's spheres
- History of American newspapers
- History of journalism
- Journalism school
- Journalism ethics and standards
- Journalism genres
- Lists of journalists
- List of journalism awards
- Non-profit journalism
- Journalistic objectivity
- Sensor journalism
- Sports journalism
Reviews
- American Journalism Review
- Columbia Journalism Review
- Health News Review
- Ryerson Review of Journalism
Academic journals
- Journalism Practice
- Journalism Studies
- Journalism
- Digital Journalism
Remove ads
References
Further reading
External links
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads