Oṣù Kẹta
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Oṣù (March) ní èdè gẹ̀ẹ́sì jẹ́ oṣù kẹta tí a tún mọ̀ sí oṣù Ẹrẹ́na nínú kàlẹ́ńdà Julian àti Gregorian. Ọjọ́ mẹ́tàlélọ́gbọ̀n ló wà nínú rẹ̀. Ní Àríwá Àgbáyé, ọjọ́ àkọ́kọ́ oṣù Ẹrẹ́na ni ìgbà ìrúwé máa ń bẹ̀rẹ̀. Ìṣojú òṣùpá ní oṣù èrèlè máa ń wáyé ní ogúnjọ́ àti ọjọ́kọkànlélógun èyí tó máa ń fi hàn pé ọ̀sán ti bẹ̀rẹ̀ ní àríwá àgbáyé àti ìgbà ìrúwé ti bẹ̀rẹ ní gúsù àgbáyé, níbi tí oṣù kẹsàn-an ti bá oṣù kẹta mu ní àárín àgbáyé mu.
|
2025 | ||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
| Àdàkọ:Calendar/Sun1stMonthStartỌjọ́rú |
|
|
| |||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
| Àdàkọ:Calendar/Sun1stMonthStartỌjọ́bọ̀ |
|
|
| |||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
|
Àdàkọ:Calendar/Sun1stMonthStartỌjọ́rú |
|
| |||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
Remove ads
Ìtàn


Orúkọ oṣù Ẹrẹ́na wá látinú orúkọ oṣù Martius, ìyẹn oṣù àkọ́kọ́ nínú kàlẹ́ńdà àwọn ará Róòmù. Orúkọ rẹ̀ wá látinú orúkọ Mars, ọlọ́run ogun Róòmù, tó sì jẹ́ baba ńlá àwọn ará Róòmù nípasẹ̀ àwọn ọmọ rẹ̀, Romulus àti Remus. Oṣù rẹ̀ tó ń jẹ́ Martius ni ìbẹ̀rẹ̀ ogun, àwọn ayẹyẹ tí wọ́n ń ṣe fún un lóṣù náà sì ń wáyé ní oṣù kẹwàá, nígbà tí àwọn ayẹyẹ náà báti parí. Martius jẹ́ oṣù àkọ́kọ́ nínú kàlẹ́ńdà Róòmù tìtí di Ọdún àádọ́jọ lé mẹ́ta ṣáájú ikú olùwa (153 BC), àti àwọn ayẹyẹ oríṣǐríṣǐ tí àwọ́n ẹlẹ́sìn máa ń ṣe ní abala àkọ́kọ́ oṣù náà ni wọ́n fi ń sọ orí ayẹyẹ ọdún tuntun. Kódà ní ìparí ìgbàanì, àwọn àwòrán àwọn ará Róòmù máa ń ṣàpèjúwe oṣù Ẹrẹ́na nígbà míì gẹ́gẹ́ bíi oṣù àkọ́kọ́.
Ọjọ́ kìní oṣù kẹta jẹ́ òǹkà ìbẹ̀rẹ̀ ọdún nílẹ̀ Rọ́ṣíà títí di òpin ọ̀rúndún kẹẹ̀ẹ́dógún. Ilẹ̀ Gẹẹsi àti àwọn ìlú tó yiká máa ń lo ọjọ́ karùndínọ́gbọ̀n oṣù kẹta títí di ọdún 1752, nígbàtí wọ́n padà gba kàlẹ́ndà Gregorian (ìbẹ̀rẹ̀ ọdún nílẹ̀ gẹ̀ẹ́sì máa ń bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ kẹfà oṣù, èyí tó ṣe déédé pẹ̀lú ọjọ́ karùndínọ́gbọ̀n nínú kàlẹ́ńdà Julian tẹ́lẹ̀). Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn àṣà mííràn, fún àpẹẹrẹ ní ilẹ̀ Iran, tàbí Etiopia, máa ń ṣe ayẹyẹ ìbẹ̀rẹ̀ ọdún titun ní Oṣù Kẹta. [1]
Ọ̀sù Ẹrẹ́na ni oṣù àkọ́kọ́ tí ìrúwé máa ń wáyé ní àríwá àgbáyé (Àríwá Amẹ́ríkà, Ilẹ̀ Yúróòpù, Ilẹ̀ Éṣíà àti apá kan ní ilẹ̀ Áfíríkà) àti oṣù àkọ́kọ tí ìrúwé á máa wáyé ní àgbègbè gúúsù àgbáyé.
Àwọn ayẹyẹ àwọn ará Róòmù ìgbàanì tí wọ́n ń ṣe ní oṣù Ẹrẹ́na ni Agonium Martiale, tí wọ́ n ṣe ní ọjọ́ kínní oṣù Ẹrẹ́na, Ọjọ́ kẹrìnlá, àti ọjọ́ kẹtàdínlógún, Matronalia, tí wọ̣n ń ṣe ní ọjọ́ kíní, Junonalia, tí wọ́n ń ṣayẹyẹ rẹ̀ ní ọjọ́ keje, Equirria, tí wọ̀n ń ṣe ní ọjọ́ kẹrìnlá, Mamuralia, tí wọn ń ṣe yálà ní ọjọ́ kẹrìnlá tàbí ọjọ́ karùndínlógún, Hilaria ní oṣù karùndínlógún àti lẹ́yìn náà títí di ọjọ́ kejìlélógún sí ìkejìdínlọ́gbọ̀n, Argei, tí wọ̃n ń ṣe ní ọjọ́ kẹrìndínlógún sí ìkẹtàdínlógún, Liberalia àti Bacchanalia, tí a ń ṣe ní ọjọ́ kẹtàdínlógún, Quinquatria, tí a ń ṣe ní ọjọ́ kọkàndínlógún sí ọjọ́ kẹtàlélógun, àti Tubilustrium, tí a ń ṣayẹyẹ rẹ̀ ní ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù Ẹrẹ́na bákan náà. Àwọn ọjọ́ wọ̀nyí kò bá kàlẹ́ńdà Gregory ìgbàlódé mu.
Remove ads
Àwọn orúkọ mìíràn
Ní Ilẹ̀ Finnish, a máa ń pè é ní maaliskuu, èyí tí wọ́n gbà gbọ́ pé ó wá látọ̀dọ̀ maallinen kuu. Kuu túmọ̀ sí oṣù ilẹ̀, ó sì lè tọ́ka sí ìgbà tí "ilẹ̀ ayé" kókọ́ fara hàn jáde lábẹ́ òtútù yìnyín. Ní èdè Ukraine, wọ́n ń pè é ní березень/berezenʹ, tó túmọ̀ sí igi àyín, wọ́ n sì ń pè é lédè Czech ní březen. Àwọn orúkọ tí wọ́n fi ń pe oṣù Ẹrẹ́na ní orúkọ oṣù Lent ti ìlú Saxon, èyí tó jẹ́ orúkọ tí wó́n fi ń pè ní oṣù Ẹrẹ́na tí ń jẹ́ ìsọ̀rí ọjọ́ àti bí ọjọ́ ṣe ń gùn sí i ní àsẹ̀yìnwá àsẹ̀rẹ̀, àti orúkọ tí wó̀n ń pè ní Lent. Àwọn ará Saxony tún pe oṣù èrèlé ní Rhed-monat tàbí Heth-monath (tí ó wá látọ̀dọ̀ òrìṣábìrin wọn Rhedam / Hreth), àwọn Angles sì ń pèé ní Hyld-monath, èyí tó di Lide ní èdè Gẹ̀ẹ́sì. Ní orílẹ̀-èdè Croatia, wọ́n ń pè é ní Ožujak. Ní orílẹ̀ èdè Slovenia, orúkọ ìbílẹ̀ tí wọ́n ń pè ní sušec, èyí tó túmọ̀ sí oṣù tí ilẹ̀ gbẹ tí àǹfàní sì wà fún iṣẹ́ ọ̀gbin. Wọ́n kọ orúkọ náà fún ìgbà àkọ́kọ́ ní ọdún 1466 nínú ìwé àfọwọ́kọ Škofja Loka. A tún lo àwọn orúkọ mìíràn, bí àpẹẹrẹ brezen àti breznik, "èyì tí ó jẹ oṣù àwọn igi àyín".[2] Ọ̀rọ̀ orílẹ̀ èdè Turkey Mart jẹ́ orúkọ tí wọ́n fi ń pe òrìṣà wọn èyí tí ó ń jẹ́ Mars.
Remove ads
Àwọn àmì


àwon òkúta oṣù Ẹrẹ́na ni aquamarine àti bloodstone. Àwọn òkúta wọ̀nyí ṣàpẹẹrẹ ìgboyà. Òdòdó ìbí oṣù Ẹrẹ́na ni daffodil. [3] Awọn àmì ìràwọ̀ oṣù èrèlé ni ẹja (Pisces) titi di ogúnjọ́ tí àmì àgbò (Aries) yóò tẹ̀síwájú láti ọjọ́ kọkànlélógún. [4]
Àwọn Ìṣẹ̀tọ́
Àlà yìí kò ní dandan kó sọ pé ó ní ipò àṣẹ tàbí pé ó ní ìfọkànsìn àpapọ̀.
Gbogbo osù
- Nínú àṣà Kátólíìkì, oṣù Ẹrẹ́na ni Ọdún Àlùfáà Mímọ́ Jósẹ́fù.
- Oṣù ìlanilọ́yẹ̀ lórí àìsàn ìràn-inú (ìgbà tí a máa ń ṣe é lágbàáyé)
- Oṣù ońjẹ aṣara lóore ní Orílẹ̀-Èdè (Kánádà)
- Ìgbà àlàáfíà: ọgbọ̀n ọjọ́ oṣù kíní sí Ọjọ́ kẹrin oṣù kẹrin (ìgbà tí a máa ń ṣe é lágbàáyé)
- Oṣù Ìtàn Àwọn Obìnrin (Ọsirélíà, Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì, Orílẹ̀ èdè Amẹ́ríka)
- Oṣù tó ń sọ Ipa ti Awọn Obìnrin nínú Ìtàn (Philippines)
Àwọn ará Amẹ́ríkà
- Cerebral Palsy Awareness Month[5]
- Irish-American Heritage Month
- Multiple Sclerosis Awareness Month
- Music in our Schools Month
- National Athletic Training Month
- National Bleeding Disorders Awareness Month
- National Celery Month
- National Frozen Food Month
- National Kidney Month
- National Nutrition Month
- National Professional Social Work Month
- National Reading Awareness Month
- Youth Art Month
Àwọn tí kì í ṣe ọmọ Gíríìkì
(Gbogbo àwọn àṣà àwọn Bahá'í, àwọn ẹlẹ́sìn Ísálì àtÀwọn Júù máa ń bẹ̀rẹ̀ nígbà tí oòrùn bá wọ̀ kí ọjọ́ tá a mẹ́nu kàn tó dé, wọ́n sì máa ń parí lọ́jọ́ tí oòrùn ti wọ̀ láìjẹ́ pé a ti sọ ohun tó yàtọ̀.)
Àwọn ohun èlò tó lè gbé
- Àwọn àjọyọ̀ Kristẹni Ìlà Oòrùn tó ṣeé gbé
- Àwọn àṣà Kristẹni tó ṣeé gbé ní Ìwọ̀ Oòrùn ayé
- Ọjọ́ Àtijọ́ Ọja (Amẹ́ríkà): ọjọ́ kọkànlélógún
- Ọjọ́ pínnre làáare níbi owó Ọ̀yà (Orílẹ̀-Èdè Amẹ́ríkà): ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n
Ọjọ́ Àìkú àkọ́kọ́
- Ọjọ́ Àwọn Ọmọdé (New Zealand)
Ọ̀sẹ̀ àkọ́kọ́, láti ọjọ́ kíní sí ìkeje
- Ọ̀sẹ̀ Owó Kárí Ayé
Ọjọ́ iléèwé tó sún mọ́ ọjọ́ kejì, oṣù kẹta
- Àjọyọ̀ Àwọn Òǹkàwé nílẹ̀ Amẹ́ríkà
Ọjọ́ Ajé àkọ́kọ́
- Ọjọ́ Casimir Pulaski (Amẹ́ríkà)
Ọjọ́ ìṣẹ́gun àkọ́kọ́
- Ọjọ́ Àwọn Bàbá bàbá (Faranse)
Ọjọ́bọ̀ àkọ́kọ́
- Ọjọ́ Ìwé Àgbáyé (Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì àti Ireland)
- Ọjọ́ ìmọ̀ ẹ̀kọ́ ìṣirò Wà Lágbàáyé
Ọjọ́ Ẹtì àkọ́kọ́
- Ọjọ́ Ìmọrírì Àwọn Òṣìṣẹ́ (Amẹ́ríkà, Kánádà)
Ọjọ́ Àìkú kejì
- Àkókò tí wọ́n fi ń ṣọ́ òru bẹ̀rẹ̀ (orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà àti Kánádà)
Ọ̀sẹ̀ ọjọ́ kẹjọ sí ìkẹrìnlá
- Ọ̀sẹ̀ Àwọn Obìnrin tó ń ṣiṣẹ́ nílé iṣẹ́ ọkọ̀ òfúrufú lágbǎyé
Ọjọ́ ajé tí ó sún mọ́ ọjọ́ kẹsàn-án, àyàfi tí ọjọ́ kẹsàn-án bá bọ́ sí ọjọ́ Àbámẹ́ta
- Ọjọ́ Ìbùkún Àgbà (Belize)
Ọjọ́ Ajé kejì
- Ọjọ́ Canberra (Ọsirélíà)
- Ọjọ́ Àjọ Ìbílẹ̀
Ọjọ́rú kejì
- Ọjọ́ Ìṣelọ́ṣọ̀ọ́ (Líbéríà)
- Ọjọ́ Tí Kò Sí fífa nǹkan (Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì)
Ọjọ́bọ keji
- Ọjọ́ kíndìnrín lágbàáyé
Ọjọ́ Ẹtì ti ọ̀sẹ̀ kejì tó pé ní oṣù
- Ọjọ́ Oorun lágbàáyé
Ọ̀sẹ̀ kẹta nínú oṣù kẹta
- Ọ̀sẹ̀ gbígbógunti májèlé(Ìpínlẹ̀-Èdè Amẹ́ríkà)
Ọjọ́ ajé Kẹta
- Ọjọ ibi ti Benito Juarez ( Mexico )
Ọjọ́ kọkàndínlógún, àyàfi tí ọjọ́ kẹkàndínlógún bá jẹ́ ọjọ́ Àìkú, yóò jẹ́ ogúnjọ oṣù kẹta
- Ọjọ́ Baba Jósẹ́fù ará Násárétì (ìyẹn Ìsìn Kristẹni Ìwọ̀ Oòrùn àgbáyé).
- Ọjọ́ Àwọn Bàbá (Sépà, Potogí, Ítálì, Honduras àti Bolivia)
- Las Fallas, tí wọ́n máa ń ṣe lọ́sẹ̀ tó ṣáájú ọjọ́ kọkàndínlógún.(Valencia)
- "Ìpadàbọ ti Ọ̀kọ̀ọ̀kan", ìyẹn ayẹyẹ tí wọ́n máa ń ṣe lọ́dọọdún láti fi rántí ìgbà tí àwọn ọ̀kọ̀ọ́kan náà pa dà sí Mission San Juan Capistrano ní Kalifornia.
Ọjọ́rú kẹta
- Àyájọ́ ọjọ́ àwọ́n igi (Netherlands)
Ìṣojú òṣùpá oṣù Kẹta: Ogúnjọ́ oṣù kẹta
- Nowruz, Ọdún titun àwọn ará ilẹ̀ Iran. (A ṣe àkíyèsí rẹ̀ káríayé)
- Chunfen ( Ila-oorun Asia )
- Dísablót (díẹ̀ nínú àwọn ẹgbẹ́ Asatru )
- Earth Equinox Day
- Equinox ti awọn Ọlọrun/Ọdun Tuntun ( Thelema )
- Higan ( Japan )
- International Afirawọ Day
- Mabon ( Gusu ẹdẹbu ) ( Neo-keferi )
- Ostara ( Ariwa Aye ) ( Neo-keferi )
- Shunbun no Hi ( Japan )
- Sigrblot ( The Troth )
- Wiwa Igba otutu ( Apejọ Ọfẹ Asatru )
- Ọjọ-Oorun-Earth ( Amẹrika )
- Ọjọ Vernal Equinox / Koreisai ( Japan )
- Ọjọ Ìtàn Àgbáyé
Ọjọ́ Ajé kẹrin
- Ọjọ́ Òṣìṣẹ́ (Erékúsù Kérésìmesì, Ọsirélíà)
Ọjọ́ Ìṣẹ́gun kẹrin
- Ọjọ́ Ìkìlọ̀ fún Àìsàn Àtọ̀gbẹ nílẹ̀ Amẹ́ríkà (Amẹ́ríkà)
Ọjọ́ Àbámẹ́ta tó kẹhìn
- Wákàtí Ayé (à ń ṣe ayẹyẹ rẹ̀ lágbááyé)
Ọjọ́ àìkú tó kẹ́hìn
- Àkókò tí oòrùn ma ń pọ̀ ní ilẹ̀ Yúróòpù
Ní ọjọ́ Monday tó kọjá
- Ọjọ́ Seward (Alaska, Orílẹ̀-Èdè Amẹ́ríkà)
Àwọn ọjọ́ tí ó ti wà ní àkọsílẹ̀
- March 1
- Baba Marta (Bulgaria),
- Beer Day (Iceland)
- Commemoration of Mustafa Barzani's Death (Iraqi Kurdistan)
- Heroes' Day (Paraguay)
- Independence Day (Bosnia and Herzegovina)
- Mărțișor (Romania and Moldavia)
- National Pig Day (United States)
- Remembrance Day (Marshall Islands)
- Saint David's Day (Wales)
- Samiljeol (South Korea)
- Self-injury Awareness Day (International observance)
- World Civil Defence Day
- March 2
- National Banana Creme Pie Day (United States)
- National Reading Day (United States)
- Omizu-okuri ("Water Carrying") Festival (Obama, Japan)
- Peasant's Day (Burma)
- Texas Independence Day (Texas, United States)
- Victory at Adwa Day (Ethiopia)
- March 3
- Hinamatsuri (Japan)
- Liberation Day (Bulgaria)
- Martyr's Day (Malawi)
- Mother's Day (Georgia)
- National Canadian Bacon Day (United States)
- Sportsmen's Day (Egypt)
- World Wildlife Day
- March 4
- National Grammar Day (United States)
- St Casimir's Day (Poland and Lithuania)
- March 5
- Custom Chief's Day (Vanuatu)
- Day of Physical Culture and Sport (Azerbaijan)
- Learn from Lei Feng Day (China)
- National Absinthe Day (United States)
- National Cheez Doodle Day (United States)
- St Piran's Day (Cornwall)
- March 6
- European Day of the Righteous ( Europe)
- Foundation Day (Norfolk Island)
- Independence Day (Ghana)
- March 7
- Liberation of Sulaymaniyah (Iraqi Kurdistan)
- National Crown Roast of Pork Day (United States)
- Teacher's Day (Albania)
- March 8
- International Women's Day
- International Women's Collaboration Brew Day
- Mother's Day (primarily Eastern Europe, Russia, and the former Soviet bloc)
- National Peanut Cluster Day (United States)
- National Potato Salad Day (United States)
- International Women's Day
- March 9
- National Crabmeat Day (United States)
- National Meatball Day (United States)
- Teachers' Day (Lebanon)
- March 10
- Harriet Tubman Day (United States of America)
- Holocaust Remembrance Day (Bulgaria)
- Hote Matsuri (Shiogama, Japan)
- National Blueberry Popover Day (United States)
- National Mario Day (United States)
- National Women and Girls HIV/AIDS Awareness Day (United States)
- Tibetan Uprising Day (Tibetan independence movement)
- March 11
- Day of Restoration of Independence of Lithuania
- Johnny Appleseed Day (United States)
- Moshoeshoe Day (Lesotho)
- Oatmeal Nut Waffles Day (United States)
- March 12
- Arbor Day (China)
- Arbor Day (Taiwan)
- Aztec New Year
- Girl Scout Birthday (United States)
- National Baked Scallops Day (United States)
- National Day (Mauritius)
- Tree Day (North Macedonia)
- World Day Against Cyber Censorship
- Youth Day (Zambia)
- March 13
- Anniversary of the election of Pope Francis (Vatican City)
- Kasuga Matsuri (Kasuga Grand Shrine, Nara, Japan)
- L. Ron Hubbard's birthday (Scientology)
- Liberation of Duhok City (Iraqi Kurdistan)
- National Coconut Torte Day (United States)
- March 14
- Multiple Sclerosis Awareness Week March 14 to March 20 (United States)
- Pi Day
- White Day (Asia)
- March 15
- March 16
- March 17
- Children's Day (Bangladesh)
- Evacuation Day (Massachusetts) (Suffolk County, Massachusetts)
- Saint Patrick's Day (Ireland, Irish diaspora)
- March 18
- Anniversary of the Oil Expropriation (Mexico)
- Flag Day (Aruba)
- Gallipoli Memorial Day (Turkey)
- Men's and Soldiers' Day (Mongolia)
- Teacher's Day (Syria)
- March 19
- March 20
- Feast of the Supreme Ritual (Thelema)
- Great American Meatout (United States)
- International Day of Happiness (United Nations)
- Independence Day (Tunisia)
- International Francophonie Day (Organisation internationale de la Francophonie), and its related observance:
- UN French Language Day (United Nations)
- Liberation of Kirkuk City (Iraqi Kurdistan)
- National Native HIV/AIDS Awareness Day (United States)
- World Sparrow Day
- March 21
- Arbor Day (Portugal)
- Birth of Benito Juárez, a Fiestas Patrias (Mexico)
- Harmony Day (Australia)
- Human Rights Day (South Africa)
- Independence Day (Namibia)
- International Colour Day (International observance)
- International Day for the Elimination of Racial Discrimination (International observance)
- International Day of Forests (International observance)
- Mother's Day (most of the Arab world)
- National Tree Planting Day (Lesotho)
- Truant's Day (Poland, Faroe Islands)
- World Down Syndrome Day (International observance)
- World Poetry Day (International observance)
- World Puppetry Day (International observance)
- Youth Day (Tunisia)
- March 22
- Emancipation Day (Puerto Rico)
- World Water Day
- March 23
- Day of the Sea (Bolivia)
- Ministry of Environment and Natural Resources Day (Azerbaijan)
- National Chips and Dip Day (United States)
- Pakistan Day (Pakistan)
- Promised Messiah Day (Ahmadiyya)
- World Meteorological Day
- March 24
- Commonwealth Covenant Day (Northern Mariana Islands, United States)
- Day of Remembrance for Truth and Justice (Argentina)
- Day of National Revolution (Kyrgyzstan)
- International Day for the Right to the Truth Concerning Gross Human Rights Violations and for the Dignity of Victims (United Nations)
- National Tree Planting Day (Uganda)
- Student Day (Scientology)
- World Tuberculosis Day
- March 25
- Anniversary of the Arengo and the Feast of the Militants (San Marino)
- Cultural Workers Day (Russia)
- Empress Menen's Birthday (Rastafari)
- EU Talent Day (European Union)
- Feast of the Annunciation (Christianity), and its related observances:
- Lady Day (United Kingdom) (see Quarter Days)
- International Day of the Unborn Child (international)
- Mother's Day (Slovenia)
- Waffle Day (Sweden)
- Freedom Day (Belarus)
- International Day of Remembrance of the Victims of Slavery and the Transatlantic Slave Trade
- International Day of Solidarity with Detained and Missing Staff Members (United Nations General Assembly)
- Maryland Day (Maryland, United States)
- Revolution Day (Greece)
- Struggle for Human Rights Day (Slovakia)
- Tolkien Reading Day (Tolkien fandom)
- March 26
- Independence Day (Bangladesh)
- Khordad Sal (Zoroastrianism)
- Martyr's Day or Day of Democracy (Mali)
- Prince Kūhiō Day (Hawaii, United States)
- Purple Day (Canada and United States)
- March 27
- Armed Forces Day (Myanmar)
- International whisk(e)y day
- World Theatre Day (International)
- March 28
- Commemoration of Sen no Rikyū (Schools of Japanese tea ceremony)
- Serfs Emancipation Day (Tibet)
- Teachers' Day (Czech Republic and Slovakia)
- March 29
- Boganda Day (Central African Republic)
- Commemoration of the 1947 Rebellion (Madagascar)
- Day of the Young Combatant (Chile)
- Youth Day (Taiwan)
- March 30
- Land Day (Palestine)
- National Doctors' Day (United States)
- Spiritual Baptist/Shouter Liberation Day (Trinidad and Tobago)
- World Idli Day
- March 31
- César Chávez Day (United States)
- Culture Day (Public holidays in the Federated States of Micronesia)
- Day of Genocide of Azerbaijanis (Azerbaijan)
- Freedom Day (Malta)
- International Transgender Day of Visibility
- King Nangklao Memorial Day (Thailand)
- National Backup Day (United States)
- National Clams on the Half Shell Day (United States)
- Thomas Mundy Peterson Day (New Jersey, United States)
- Transfer Day (US Virgin Islands)
Remove ads
Àwọn àlàyé
Àwọn ìjápọ̀ àgbáyé
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads