Moji Olaiya

òṣèré orí ìtàgè àti akọrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjírírà From Wikipedia, the free encyclopedia

Remove ads

Mojí Ọláìyá (bíi ní Ọjọ́ kẹtàdínlọ̀gbọ̀n Oṣù kejì ọdùn 1975 – ọjọ́kẹtàdínlogún Oṣù Kàrún-ún ọdún 2017) jẹ́ eléré orí-ìtàǵe Yorùbá ọmọ orílẹ̀-èdè Naijiria.[1]

Quick Facts Ọjọ́ìbí, Aláìsí ...

Iṣẹ́ rẹ̀

Mojí jẹ́ ọmọ Victor Olaiya gbajú-gbajà ọ̀kọrin highlife ilé Nàìjíríà. Mojí Õláìyá bẹ̀rẹ̀ eré orí-ìtàgé rẹ̀ pẹlú ilé iṣẹ́ Wale Adenuga Super Story.[2] Ó kopa to laami laaka ninu awon osere Nollywood Yoruba ati Geesi lapapo.[3] Mojí di gbajúgbajà òṣèré sinimá àgbéléwò láàrin àwọn akẹgbẹ́ rẹ̀ tó kù látàrí ipa rẹ̀ tó kó nínú eré Gẹ̀ẹ́sì tí a mọ̀ sí No Pains No Gains, ní èyí ti ó tí kópa gẹ́gẹ́ bí Ìrètí, Sade Blade (2005), Nkan adun (2008) ati Omo iya meta leyi (2009). Bakan naa lo tun han ninu Agunbaniro. ni odun 2003. Won tun yaan fun ami eye idani-lola ti (The Reel Award Best Supporting Actress of the Year), bakan naa lo tun jawe olubori ninu idije ami eye 'Oserebinrin to dara julo' (Best New Actress Award) ni osu kejo odun 2016.[4]


ni odun 2016, Moji se fiimu ara kan jade,ti o pe ni, Iya Okomi,[5] to safiha awon osere akegbe re to ku bii: Foluke Daramola àti Funsho Adeolu, ni eyi ti won safihan re akoko ni gbongan ni Ilu-Eko ni osu keje.[6]

Remove ads

Igbesi Aye re

Moji Olaiya se igbeyawo pelu Bayo Okesola ni odun 2007, ko pe ko jina won korawon sile.[7][8][9] Moji yi pada lati esin Kiristeni si esin Islam ni odun 2014 funra re.[10][11]

O ku ni ojo-ketadinlogun osu karun-un odun 2017, latari aisan Okan ni Ilu Canada, leyin osu meji ti o bimo keji.[12] ki olorun o bawa fOrun ke. O digba O di gbere.

Awon Ere ti O ti Kopa

  • Aje nile Olokun
  • Ojiji Aye
  • Apaadi
  • Omo Iya Meta leyi (2009)
  • Nkan adun (2008)
  • Sade Blade (2005)

Awon Itoni

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads