Okezie Ikpeazu

Olóṣèlú From Wikipedia, the free encyclopedia

Remove ads

Okezie Victor Ikpeazu (ojoibi 18 Osu Kewa 1964) ni Gomina Ipinle Abia lowolowo, o bo si ori aga ni May 29, 2015. O je omo egbe oselu Peoples Democratic Party.[1][2] Won tun diboyan si ipo gomina Ipinle Abia ninu idibo to waye ni March 9th, 2019.[3]

Quick facts 9th Gómìnà ìpínlẹ̀ Abia, Deputy ...


Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads