Theodore Orji
Olóṣèlú Nàìjíríà From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Theodore Ahamefule Orji ni wọ́n bí ní 11/11/1950. Ó jẹ́ olóṣèlú ará ilẹ̀ Nàìjíríà àti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Abia láti ọdún 2007 títí dé 2015. Ní ìgbàkan rí ó jẹ́ òṣìṣẹ́ ìjọba àti pé ó jẹ́ olórí àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba ní abẹ́ Gómìnà Orji Uzor Kalu. Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú PDP, lọ́wọ́lọ́wọ́.

![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Remove ads
Àwọn Ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads