Orji Uzor Kalu

Olóṣèlú Nàìjíríà From Wikipedia, the free encyclopedia

Remove ads

Orji Uzor Kalu (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kẹrin ọdún 1960) jẹ́ olóṣèlú ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Abia lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ṣáà méjì ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ló lò gẹ́gẹ́ bí Gómìnà ìpínlẹ̀ Abia. Lọ́dún 2019, ó díje dùpò Sínétọ̀ lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress, ó sìn wọlé. Lọ́jọ́ karùn-ún oṣù Kejìlá ọdún 2019, ilé ẹjọ́ dá a lẹ́bi ẹsùn jìbìtì owó tí ìjọba àpapọ̀ fi kàn án, wọ́n sì fi i sẹ́wọ̀n ọdún méjìlá gbáko. [1]

Quick facts 7th Gómìnà ìpínlẹ̀ Abia, Asíwájú ...



Remove ads

Àwọn Ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads