Rema
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Divine Ikubor (ibí 1 May 2000),Orúkọ orí itage rẹ̀ ń jẹ́ REMA, akọrin ti orílẹ-èdè Nàìjíríà. Ayé mo Rema nígbà tí ó gbé orin tí àkọlé rẹ ń jẹ́ "Iron Kan", èyí tí ó jẹyọ nínú summer playlist ti Barack Obama ni ọdún 2019 [1] Bákan náà ní 2019, Ó sí fọwọ́ sí láti bá Jonzing World ṣíṣe, èyí tí ó wa labẹ Mavin Records.[3]
Remove ads
Ìbẹ́rẹ́pẹ́pẹ́ Ayé
Divine Ikubor jẹ́ ọmọ tí wón bí sí ilé bí ìgbàgbọ Kíìtẹ́nì ni ìpínlẹ̀ Benin ni orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[4]Bí o ṣé ń dàgbà ní ọ má ń kọ Orin, béè sì ní ọ má ń Rap, nígbà tí ó wà ní ilé ìwé Sẹ́kọ́ńdírì. Ó ká ìwé alákọ̀bẹ́rẹ́ tí primary àti Sẹ́kọ́ndiri rẹ ni Ighile Group of School ni ipinlẹ Edo.[5][6]
Àwọn orin rẹ̀
Àwo-orin
Atojo Àwo-orin
- Rema Compilation (2020)
Orin mìíràn
- Rema (2019)
- Freestyle EP (2019)
- Bad Commando[9] (2019)
Orin àdákọ
- "Dumebi" (2019)
- "Why" (2019)
- "Dumebi" (2019) [10]
- "Corny" (2019)
- "Boulevard" (2019)
- "American Love" (2019)
- "Spiderman" (2019)
- "Trap Out the Submarine" (2019)
- "Bad Commando" (2019)
- "Lady" (2019)
- "Rewind" (2019)
- "Spaceship Jocelyn" (2019)
- "Dumebi Remix" (featuring Becky G) (2020)
- "Beamer (Bad Boys)" (2020)
- "Rainbow" (2020)
- "Fame" (2020)
- "Ginger Me" (2020)
- "Alien" (2020)
- "Woman" (2020)
- "Peace of Mind" (2020)
- "Bounce" (2021)
- "Soundgasm" (2021)
- "44" (featuring Bad Gyal) (2021)
- "Calm Down" (2022)
- "FYN" (2022)
Remove ads
Àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀
Àwọn Ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads