Mavin Records
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Mavin Records (tị́ a tún mọ̀ sí Supreme Mavin Dynasty)[2] jẹ́ ilé-iṣẹ́ agbórin-jáde ní ilẹ̀ Nàìjíríà tí Don Jazzy tí ń ṣe olórin àti agbórinjáde dá sílẹ̀ ní 8th May, 2012. Ilé-iṣẹ́ náà bẹ̀rẹ̀ lẹ́yìn tí òpin dé bá Mo' Hits Records, ilé-iṣẹ́ tí ń ṣe ti D'banj àti ti agbórinjáde tí a dárúkọ ṣaájú [3] Ilé-iṣẹ́ náà bí i ilé ni fún àwọn akọrin bí i Korede Bello, Dr SID, D'Prince, Di' ja, Johnny Drille, Ladipoe, DNA Twins, Rema, Arya Starr, Magixx & Boy Spyce. A tún ma rí àwọn agbórinjáde bí i Jazzy fúnra rẹ̀, Altims àti Baby Fresh.[4] Ní 2014, DJ Big N jẹ́ DJ àkọ́kọ́ tí ile-iṣẹ́ náà ní. Tiwa Savage, Wande Coal, Reekado Banks àti Iyanya ni wọ́n ti wà ní ilé-iṣẹ́ náà rí gẹ́gẹ́ bí i olórin.[5] Ní 8th May, 2012, ilé-iṣẹ́ náà ṣe àgbéjáde àtòjọ awo-orin Solar Plexus.[6] Ní January 2019, Kupanda Holdings, tí ń ṣe ẹ̀ka Kupanda Capital àti TPG Growth bá ilé-iṣẹ́ Mavin dòwò pọ̀ pẹ̀lú iye owó tí ó ń lọ mílíọ́ọ̀nù dollar.[7]

Remove ads
Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ
Wọ́n yan Mavin Records gẹ́gẹ́ bí i ilé-iṣẹ́ agbórinjáde tó dára jù lọ ní ọdún 2013, lábẹ City People Entertainment Awards.[8] Wọ́n sí tún gba àmì-ẹ̀yẹ ní ọdún 2014 lọ́wọ́ City People Entertainment Awards.
Remove ads
Awon osere
Lowolowo
Osere ateyinwa
Remove ads
Awon agborinjade
Agborinjade lowolowo
- Don Jazzy
- Altims
- Babyfresh
DJ's
- DJ Big N
Awon atojo orin won
Awo-orin
Orin Adako
Remove ads
Àwọn Ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads