Niger Delta
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Niger Delta jẹ́ ilẹ̀ àti iyẹ̀pẹ̀ tí ó sàn láti Odò Ọya tí ó sì wà ni Gulf of Guinea ti Atlantic Ocean, Nàìjíríà.[1][2] Ó wà lórí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìpínlẹ̀ ní Nàìjíríà.


Ọ̀pọ̀lopọ̀ lọ ń gbé lórí Niger Delta, ọ̀pọ̀lọpọ̀ sì mọ ibè sí Oil Rivers nítorí ibè ni wọ́n ti ń ṣe epo Pupa ní Nàìjíríà.[3] Ibẹ̀ náà sì jẹ́ ibi tí ọ̀pọ̀lopọ̀ epo rọ̀bì.[4][5]
Remove ads
Ilẹ̀ Niger Delta
Niger Delta ní ilẹ̀ tí ó tó 70,000 km2 (27,000 sq mi), ó sì gbà tó 7.5% gbogbo ilẹ̀ Nàìjíríà. Àwọn Ìpínlẹ̀ tí ilẹ̀ náà dé ni Bayelsa, Delta, àti Ìpínlẹ̀ Rivers. Niger Delta ló pín Bight of Benin àti Bight of Bonny níyà nínú Gulf of Guinea.[6]
Àwọn ènìyàn Niger Delta[4]

Àwọn ènìyàn tí ó tó mílíọ̀nù ókànlélógbọ̀n ni ó gbé ní Niger Delta[7] àwọn ẹ̀yà tí ó wà níbè sì tó ogójì, àwọn ẹ̀yà bi Ukwuani, Abua, Bini, Ohaji/Egbema, Itsekiri, Efik, Esan, Ibibio, Annang, Oron, Ijaw, Igbo, Isoko, Urhobo, Kalabari, Yoruba, Okrika, Ogoni, Ogba–Egbema–Ndoni, Epie-Atissa àti Obolo, wọ́n sì ń sọ èdè tí ó tó ọ́ta-din-lẹwá-lé-nígba(250). Díè nínú àwọn èdè yìí ni èdè Ijaw, Ibibio-Efik, Igboid, Itsekiri, Central Delta, Edoid, àti Àwọn èdè irú Yorùbá,
Remove ads
Àwọn Ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads