Mercy Johnson

From Wikipedia, the free encyclopedia

Mercy Johnson
Remove ads

Mercy Johnson Okojie tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún 1984 (28th August 1984)jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[2][3] Sinimá àgbéléwò èdè Gẹ̀ẹ́sì àti Ìgboò ni Mercy Johnson máa ń kópa tí ó sìn gbajúmọ̀ nínú wọn.

Quick Facts Ọjọ́ìbí, Orílẹ̀-èdè ...


Remove ads

Ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀

Mercy Johnson-Okogie jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Okene ní ìpínlẹ̀ Kogi, ṣùgbọ́n Èkó ni wọ́n bíi sí, jagunjagun orí omi ni bàbá rẹ̀, Ọ̀gbẹ́ni Daniel Johnson, orúkọ ìyá ni Elizabeth Johnson. Mercy bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ ni ìlú Calabar ní ìpínlẹ̀ Cross River. Ó tún kàwé ni ìpínlẹ̀ Èkó bákà náà nígbà tí ìṣe gbé àwọn òbí rẹ̀ wà sí Èkó. Bẹ́ẹ̀ náà ló kàwé ni Port Harcourt, ní ìpínlẹ̀ Rivers.[4]

Àtòjọ díẹ̀ nínú àwọn sinimá-àgbéléwò rẹ̀

More information Year, Film ...
Remove ads

Àtòjọ àwọn àmìn ẹ̀yẹ tí ó gbà àti àwọn tí ó díje fún

More information Year, Event ...

Àwọn Ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads