Èdè Abanyom

From Wikipedia, the free encyclopedia

Remove ads

Èdè Abanyom

Quick facts Abanyom, Sísọ ní ...

Abanyom, tàbí Bakor, jẹ́ èdè tí àwọn Ekoid ń sọ, ó tún jẹ́ ọkàn lára àwọn èdè Niger -Congo. Abanyom tún jẹ́ èdè tí àwọn ará Abanyom ni Ìpínlẹ̀ Cross River ni Orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó sì tún jẹ́ ọkàn lára èdè Apá Gúsù, ó tún fẹ́ ẹ̀ sùnmọ́ èdè àwọn Bantu. Ó jẹ́ èdè alohùn tí ó ní ìsòrí èdè Niger -Congo tí ó yá rántí. Abanyom jẹ́ ọ̀kan lára ẹgbẹ́ Ikom.

Tí àwọn Agbègbè yìí wà lára wọn :Edor, Abangork, Akumabal, Abinti, Nkim, Nkum, Nkarassi 11, Nkarassi 1, Abankang, Etikpe, and Nkonfap. Abankang ni wọ́n ǹ ní Ìyá èdè fún Abanyom.

Remove ads

Àwọn Ìtọ́kasí

Orísun

Àkójọ Àwọn Èdè tí ó wà ní Orílẹ̀ Èdè Nàìjíríà

Èyí jẹ́ àtòkọ̀ àwọn onírúurú èdè tí ó wà ní Nàìjíríà tí akọ lè kà á tàbí mọ̀ tán.[1][2][3][4]

More information S/N, Language ...
Remove ads

Àwọn ìtọ́kasí

  1. Blench, Roger (2014). An Atlas Of Nigerian Languages. Cambridge: Kay Williamson Educational Foundation.
  2. Crozier, David Henry; Blench, Roger (1992). An Index of Nigerian languages. Dallas: Summer Inst of Linguistics. ISBN 9780883126110.
  3. "Ethnologue 15 report for Nigeria". archive.ethnologue.com. Archived from the original on 4 January 2015. Retrieved 2017-04-30.
  4. Kwache,IY (2016)Kamwe People of Northern Nigeria: Origin, History and Culture

Àdàkọ:Authority control

Àdàkọ:SBantoid-lang-stub

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads