Bacama language

From Wikipedia, the free encyclopedia

Remove ads

Èdè Bacama (Bachama) jẹ́ èdè Afro àti Asia papọ̀ tí ó sì lábẹ́ ìsòrí èdè Chad tí wọ́n ń sọ ní agbègbè kan tí wọ́n ń pè ní Numan ni Ìpínlẹ̀ Adamawa ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Bákan náà ni wọn ń sọ ó ní àwọn agbègbè bí Demsa, Lamurde, àti àwọn ará ìlú Bwatiye. [1] Àwọn Ẹ̀ka èdè tí ó Fera pé ní àwọn èdè bí Mulyen, Opalo, and Wa-Duku. Bachama-Yimburu sugbon wọ́n ni ohun tí ó yá wọn sọ tó. Bachama jẹ́ Èdè kan tí wọ́n fí ń ṣe kára-kátà.[2] Ó sábà máa ń jẹ́ èdè kaná pẹ̀lú èdè Bàtà.

Quick facts Sísọ ní, Ọjọ́ ìdásílẹ̀ ...
Remove ads

Òǹka

Òǹka inú èdè yìí máa na bẹ̀rẹ̀ láti òdo, wọ́n sì ń lọ márùn-ún (5) sì mẹ́wàá (10) láti kó àwọn Òǹka mìíràn:[3]

12345678910
hidokpemwakinfwottuftukoltakatukolukpefwofwotdombi hidobau

Àwọn Àpẹẹrẹ bí a tí ń kọ Bacama

  • Gibo ma ḅa ḍa motso da Pwa tsi ne ndso-nogi ka nji-nogi ka nogi. - Mark 3:35 (GWVS 1915) [4]

Àwọn Àkọsílẹ̀ wà ní Bacama

Audio Recordings in Bacama

Àwọn Àkọsílẹ̀

Àkójọ Àwọn Èdè tí ó wà ní Orílẹ̀ Èdè Nàìjíríà

Èyí jẹ́ àtòkọ̀ àwọn onírúurú èdè tí ó wà ní Nàìjíríà tí akọ lè kà á tàbí mọ̀ tán.[1][2][3][4]

More information S/N, Language ...
Remove ads

Àwọn ìtọ́kasí

Àdàkọ:Biu–Mandara languages

  1. Blench, Roger (2014). An Atlas Of Nigerian Languages. Cambridge: Kay Williamson Educational Foundation.
  2. Crozier, David Henry; Blench, Roger (1992). An Index of Nigerian languages. Dallas: Summer Inst of Linguistics. ISBN 9780883126110.
  3. "Ethnologue 15 report for Nigeria". archive.ethnologue.com. Archived from the original on 4 January 2015. Retrieved 2017-04-30.
  4. Kwache,IY (2016)Kamwe People of Northern Nigeria: Origin, History and Culture

Àdàkọ:Authority control


Àdàkọ:BiuMandara-lang-stub Àdàkọ:Nigeria-stub

Remove ads
Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads