Mẹ́tàlì álkálì
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Àwọn mẹ́tàlì álkálì ni egbe kan lori tabili idasiko awon elimenti to ni awon elimenti lithium (Li), sodium (Na), potassium (K), rubidium (Rb), caesium (Cs),[note 1] ati francium (Fr) ninu.[4] Egbe yi wa ni inu s-block lori tabili idasiko[5] nitoripe gbogbo awon metali alkali ni elektronu ode won ni inu s-orbital.[6][7][8] Awon metali alkali ni apere ijora egbe bi awon ini lori tabili idasiko,[6] pelu awon elimenti inu ti won unwuwa isejora.[6]
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Remove ads
Akiyesi
Itokasi
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads