Kopernisiomu

From Wikipedia, the free encyclopedia

Remove ads

Kopernisiomu je ìpilẹ̀ṣẹ̀ telégbògi pelu ami-idamo Cn ati nomba atomu 112. O koko je dida ni 1996 lati ile-ise iwadi sayensi Gesellschaft für Schwerionenforschung (GSI) ni orile-ede Jemani.

Quick Facts Pípè, Ìhànsójú ...
Remove ads

O n je ununbiomu tele pelu ami-idamo Uub ki IUPAC o to yi oruko re pada si Kopernisiomu ni 19 February, 2010 fun eye onimo-etoirawo ara Poland, Nicolaus Copernicus.

Remove ads

Itokasi

Loading content...
Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads