Promethium

From Wikipedia, the free encyclopedia

Promethium
Remove ads

Promethium (pípè /prɵˈmiːθiəm/, pro-MEE-thee-əm) je apilese kemika to ni ami-idamo Pm ati nomba atomu 61. O yato si awon apilese yioku nitori pe oun nika ni apilese radioalagbara leyin technetium to je titele pelu awon apilese kemika ti awon isotopu won duro sinsin.

Quick Facts Pípè, Ìhànsójú ...
Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads