Fẹ́rmíọ̀m

From Wikipedia, the free encyclopedia

Fẹ́rmíọ̀m
Remove ads

Fẹ́rmíọ̀m tabi Fermium (pípè /ˈfɜrmiəm/, FER-mee-əm) je apilese aladipapo pelu ami-idamo Fm ati nomba atomu 100. Gege bi apilese teyinuraniom onide alagbraradio giga ti eseese aktinidi, fermium nje dida nipa ddigbolu plutonium pelu awon neutroni o si je sisoloruko fun Enrico Fermi onimofisiyiki inuatomu. Fermium ni apilese teyinuraniom kejo.

Thumb
Fẹ́rímíọ̀m
Quick Facts Fermium, Pípè ...


Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads