Potassium

From Wikipedia, the free encyclopedia

Potassium
Remove ads

Pòtásíọ̀mù je elimenti kemika kan to ni ami-idamo K (latinu ede Latini Tuntun fun kalium) ati nomba atomu 19. Potasiomu je metali alkali alawo fadaka-funfun didelowo to undi oksidi kiakia ninu afefe to si yirapo mo omi gigdigidi, eyi unfa igbona jade to sana si haidrojin to unbujade ninu iyirapo na, o si unjo bi awo lilaki.

Quick Facts Pòtásíọ̀mù, Pípè ...

Nitoripe potasiomu ati sodiomu jora ni isese kemika won, awon iyọ̀ won ko se e ya sira won nibere. O di odun 1702 ko to di pe won fun ra pe opo elimenti wa ninu awon iyo won,[4] eyi je mimufidaju ni odun 1807 nigba ti potasiomu ati sodiomu je yiya sotooto latinu awon iyọ̀ otooto pelu elektrolisisi. Potasiomu inu adaye wa ninu awon iyọ̀ oniioni nikan. Nitori eyi, o wa ninu omi okun (to je 0.04% potasiomu pelu iwuwo[5][6]), o si je apa opo awon alumoni.


Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads