Kùríọ̀m

From Wikipedia, the free encyclopedia

Kùríọ̀m
Remove ads

Kùríọ̀m tabi Curium je apilese kemika alasopapo to ni ami-idamo Cm ati nomba atomu 96. Gege bi apilese teyinuraniom onide alagbararadio ti eseese aktinidi, kuriom nje mimuwaye nipa didigbolu plutonium pelu awon igbonwo alpha (awon ioni helium). O je sisoloruko fun Marie Skłodowska-Curie ati oko re Pierre.

Quick Facts Curium, Pípè ...
Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads