Bórọ̀nù ni ẹ́límẹ̀ntì kẹ́míkà kan tó ní àmì-ìdámọ̀B àti nọ́mbà átọ̀mù5. Nítorípé bórọ̀nù jẹ́ dídá pátápátá pẹ̀lu ìtúká ìrànká kọ́smíkì tí kò sì jẹ́ pẹ̀lù núkléùkíkódájọpọ̀ oníràwọ̀,[11] kò fi bẹ́ẹ̀ pọ̀ ní inú sístẹ́mù òrùn àti nínú ìgbẹ́lẹ̀ Ayé. Bórọ̀nù wọ́jọ ní Ayé pẹ̀lu ìtúsómi àwọn àdàpọ̀ rẹ̀ tí wọ́n wọ́pọ̀, èyun ùn àwọn àlùmọ́nì bóràtì. Àwọn wọ̀nyí únjẹ́ wíwà láti inú ilẹ̀ ní ilé-iṣẹ́ gẹ́gẹ́bí ìṣágbẹ, bíi bóráksì àti kẹ́rnítì.
Bórọ̀nú, tó jẹ́ títòpọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ mẹ́tálọ́ìdì, tí kò darapọ̀ bíi kẹ́míkà kò sí ní Ilé-Ayé. Ní ilé-iṣẹ́, ó ṣòro látí dá bórọ̀nù ògidì nítorípé oúndá èròjà míràn tí wọ́n ní kárbọ́nù tàbí àwọn ẹ́límẹ̀ntí míràn díẹ̀ nínú. Orísi àwọn àllótrópù bórọ̀nù lówà: bórọ̀nù amorphous boron is a brown powder and crystalline boron is black, extremely hard (about 9.5 on the Mohs scale), and a poor conductor at room temperature. Elemental boron is used as a dopant in the semiconductor industry.