Hílíọ̀mù

From Wikipedia, the free encyclopedia

Hílíọ̀mù
Remove ads

Hílíọ̀mù, Hélíọ̀m, tabi Helium (pípè /ˈhiːliəmu/, HEE-lee-əm) ni ẹ́límẹ̀ntì kẹ́míkà tó ní nọ́mbà átọ́mù 2 àti iwuwo atomu to je 4.002602, àmì ìdámọ̀ rẹ̀ ni He. O je efuufu oniatomukan, alaigbera, aláìláwọ̀, alailoorun, alainitowo, ati alailewu to siwaju ẹgbẹ́ ẹ̀fúùfù abíire ninu tabili asiko. Awon ojuami ìhó àti ìyọ́ rẹ̀ je awon ti won kerejulo larin awon ẹ́límẹ̀ntì, o si wa pere gege bi efuufu ayafi nigba to ba wa nipo lounloun. Leyin hydrogen, ohun ni elimenti keji to pojulo ni agbalaaye, o si je bi 24% gbogbo akojo elimenti ninu galaksi wa.

Quick Facts Pípè, Ìwúwo átọ̀mù Ar, std(He) ...
Hílíọ̀mù


Remove ads

Itumosi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads