Fluorínì

From Wikipedia, the free encyclopedia

Fluorínì
Remove ads

Fluorínì (play /ˈflʊərn/, /ˈflʊərɪn/, tabi /ˈflɔrʔ/) je apilese kemika pelu nomba atomu 9, to je sisoju pelu ami-idamo F. Fluorin da ide eyokan po mo ara re to ba wa bi apilese, eyi unfa owon F2 alatomumeji. F2 (fluorin) je efuufu pipon brown rodonrondon to undarapomora kiakia, onimojele. Fluorin alapilese ni o je eyi toun darapomora bi kemika ati alodiafinagbe julo larin gbogbo awon apilese. Fun apere, yio tete "jo" awon haidrokarbon nina ni igbonasi inuyara, ni iyato si bi awon haidrokarbon se un gbanaje pelu oksijin, to gbodo ni afikun okun pelu isana. Nitorie, fluorin owon lewu gidi, be ju awon halojin yiowu bi efuufu klorin onimajele lo.

Quick Facts Pípè, Ìhànsójú ...
Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads