Bẹ́rílíọ̀mù

From Wikipedia, the free encyclopedia

Bẹ́rílíọ̀mù
Remove ads

Bẹ́rílíọ̀mù ni ẹ́límẹ̀ntì kẹ́míkà tó ní àmì-ìdámọ̀ Be àti nọ́mbà átọ̀mù 4. Nítorípé bẹ́rílíọ̀mù yíówù tó bá jẹ́ kíkódájọpọ̀ ní inú àwọn ìràwọ̀ kì í pẹ́ tí ó fi túká, nítoríẹ̀ ó jẹ́ ẹ́límẹ̀ntì tó sọ̀wọ́n gidigidi ní àgbàlá-ayé ati ní Ilẹ̀-Ayé. Ó jẹ́ ẹ́límẹ̀ntì olójú-ìsopọ̀ mẹ́jì tó ṣe é rí nínú ìdàpọ̀ mọ́ àwọn ẹ́límẹ̀ntì míràn nìkan nínú àwọn àlúmọ́nì. Àwọn òkúta iyebíye pàtàkì kan tí wọ́n ní bẹ́rílíọ̀mù nínú ni bẹ́rìlì (òkúta odò, ẹ́míràldì) àti bẹ́rìlìoníwúrà. Tó bá dá wà, ó jẹ́ ẹ́límẹ̀ntì mẹ́tàlì alkalínì ilẹ̀ tó ní àwọ̀ irin-idẹ, tó lágbára, fífúyẹ́ àti rírún wẹ́wẹ́.

Quick Facts Pípè, Ìhànsójú ...
Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads