Magnésíọ̀mù

From Wikipedia, the free encyclopedia

Magnésíọ̀mù
Remove ads

Magnésíọ̀mù (pípè /mæɡˈniːziəm/, mag-NEE-zee-əm) je apilese kemika pelu ami-idamo Mg, nomba atomu 12 ati nomba isodoksijini wiwopo +2. O je onide alkalini inu ile ati apilese pipo repete julo kejo ninu igbele Aye, ninbi to ti je bi 2% fun iposi,[2] ati ikesan ni gbogbo Agbalaaye ti a mo.[3][4]

Quick Facts Pípè, Ìhànsójú ...
Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads