Alumíníọ̀mù

From Wikipedia, the free encyclopedia

Alumíníọ̀mù
Remove ads

Alumíníọ̀mù (UK: /ˌæljʊˈmɪniəm/  ( listen) a-lew-MIN-ee-əm[7]) tabi aluminomu (US: /əˈluːmɪnəm/  ( listen); e wo spelling labe) je apilese kemika kan ninu adipo boron to je funfun bi fadaka to se mo. O ni ami-idamo Al ati nomba atomu 13. Ko le yo ninu omi fun ra ara re. Aluminiomu je onide to po repetejulo ninu igbele Aye, ati iketa to po repetejulo nibe leyin oksijini ati silikoni. Ohun ni o je bi 8% bi iwuwo oju ile Aye. Aluminiomu ndarapomora mo awon kemika yioku kiakia gidigidi nitorie ko le da wa fun ra re gege bi onide. Bibeeko, a le ri ni didapo mo orisirisi awon alumoni bi 270.[8] Orisun aluminiomu ni adalu irin bauxite.

Quick Facts Pípè, Ìhànsójú ...


Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads